Tonic Solfa of Nipa Ife Olugbala Yoruba Hymn

Tonic Solfa of Nipa Ife Olugbala Yoruba Hymn

d s d r m s f m

r l t d

d s d r m s f m

r l t d

m m m f s s f m

r r r m s f m r

d s d r m s f m

r l t d

Lyrics of Nipa Ife Olugbala Yoruba Hymn

Nipa ife olugbala

ki yio si nkan

Ojurere re ki pada

ki yio si nkan

Owon l’eje t’owo wa san

Pipe ledidi or’ofe

Agbara l’owo t’ogba ni

Kole si nkan

2 Bi a wa ninu iponju

ki yio si nkan

Igbala kikun ni tawa

ki yio si nkan

Igbekele olorun dun,

 gbigbe ninu Kristi l’ere

Emi sin so wa di mimo

Kole si nkan

3 Ojo ola yio  dara

ki yio si nkan

Gbagbo le korin nnu ponji,

 ki yio si nkan

Agbe kele ‘fe baba wa

Jesu fun wa l’ohun gbogbo

Ni yiye tabi ni kiku

Ko le si nkan

Author: ScoresByKayo
I help you Score Choir Parts of Latest Gospel Songs with Tonic Solfa Notation. I break it down into Melody, Unison, Harmony and Swap. Look around to Download PDF, watch videos, request Choir Parts and you may even decide to buy me Shawarma shebi ayaf done so much for you this year?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *