Tonic Solfa of Si O Olutunu Orun Yoruba Hymn

Tonic Solfa of Si O Olutunu Orun Yoruba Hymn

s d d d

r d t t t

s l l l t d l s s m

s d d r m

m f s f m r d

Lyrics of Si O Olutunu Orun Yoruba Hymn

Si o Olutunu Orun
Fun ore at’agbara Re
A nko, Aleluya

2. Si O, ife eni t’Owa
Ninu Majemu Olorun
A nko, Aleluya

3. Si O agbara Eni ti
O nwe ni mo, t’o nwo ni san
A nko, Aleluya

4. Si O, Oluko at’ore
Amona wa toto d’opin
A nko, Aleluya.

5. Si O, Eniti Kristi ran
Ade on gbogbo ebun re
A nko, Aleluya. Amin

Author: ScoresByKayo
I help you Score Choir Parts of Latest Gospel Songs with Tonic Solfa Notation. I break it down into Melody, Unison, Harmony and Swap. Look around to Download PDF, watch videos, request Choir Parts and you may even decide to buy me Shawarma shebi ayaf done so much for you this year?

1 thought on “Tonic Solfa of Si O Olutunu Orun Yoruba Hymn

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *